Òwe 10:1 BMY

1 Àwọn òwe Sólómónì:Ọlọgbọ́n ọmọ ń mú inú baba rẹ̀ dùnṣùgbọ́n aláìgbọ́n ọmọ ń ba inú ìyá rẹ̀ jẹ́.

Ka pipe ipin Òwe 10

Wo Òwe 10:1 ni o tọ