Òwe 10:18 BMY

18 Ẹni tí ó pa ìkórìíra rẹ̀ mọ́ jẹ́ òpùrọ́ẹni tí ó sì ń báni jẹ́ jẹ́ aláìgbọ́n.

Ka pipe ipin Òwe 10

Wo Òwe 10:18 ni o tọ