Òwe 10:23 BMY

23 Aláìgbọ́n a máa ní inú dídùn sí ìwà búburúṣùgbọ́n olóye ènìyàn a máa ní inú dídùn sí ọgbọ́n.

Ka pipe ipin Òwe 10

Wo Òwe 10:23 ni o tọ