5 Òdodo aláìlẹ́gàn ṣe ọ̀nà tààrà fún wọnṣùgbọ́n ìwà búburú ènìyàn búburú yóò fàá lulẹ̀.
6 Òdodo ẹni ìdúró ṣinṣin gbà wọ́n làṣùgbọ́n ìdẹkùn ètè búburú mú aláìsòótọ́.
7 Nígbà tí ènìyàn búburú bá kú, ìrètí rẹ̀ a parungbogbo ohun tó ń fojú sọ́nà fún nípa agbára rẹ̀ já sófo.
8 A gba olódodo kúrò lọ́wọ́ ibidípò o rẹ̀, ibi wá sórí ènìyàn búburú.
9 Aláìmọ̀ Ọlọ́run fi ẹnu rẹ̀ ba aládùúgbò rẹ̀ jẹ́,ṣùgbọ́n nípasẹ̀ ìmọ̀ Olódodo sá àsálà.
10 Nígbà tí Olódodo ń gbèrú, ìlú a yọ̀nígbà tí ènìyàn búburú parun, ariwo ayọ̀ gba ìlú kan.
11 Nípaṣẹ̀ ìbùkún, Olódodo a gbé ìlú ga:ṣùgbọ́n nípaṣẹ̀ ẹnu ènìyàn búburú, a pa ìlú run.