Òwe 12:23 BMY

23 Ènìyàn Olóye fi ìmọ̀ rẹ̀ pamọ́ sínú ara rẹ̀ṣùgbọ́n ọkàn ènìyàn búburú ń gbé ìwà òmùgọ̀ jáde.

Ka pipe ipin Òwe 12

Wo Òwe 12:23 ni o tọ