Òwe 15:25 BMY

25 Olúwa fa ilé onígbéraga ya lulẹ̀,Ṣùgbọ́n ó pa ààlà opó mọ́ láìyẹ̀.

Ka pipe ipin Òwe 15

Wo Òwe 15:25 ni o tọ