Òwe 15:6 BMY

6 Ilé olódodo kún fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ohun ìṣúra,ṣùgbọ́n èrè àwọn ènìyàn búburú ń mú ìyọnu wá fún wọn.

Ka pipe ipin Òwe 15

Wo Òwe 15:6 ni o tọ