Òwe 17:2 BMY

2 Ọlọ́gbọ́n ìránṣẹ́ yóò ṣàkóso adójútini ọmọ,yóò sì pín ogún gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan nínú àwọn ọmọ.

Ka pipe ipin Òwe 17

Wo Òwe 17:2 ni o tọ