Òwe 17:5 BMY

5 Ẹni tí ó fi talákà ṣe yẹ̀yẹ́ kórìíra ẹlẹ́dàá talákà náàẹnikẹ́ni tí ń yọ̀ torí ìyọnu kò ní lọ láìjìyà.

Ka pipe ipin Òwe 17

Wo Òwe 17:5 ni o tọ