Òwe 18:22 BMY

22 Ẹni tí ó rí aya fẹ́, rí ohun rere,Ó sì gba ojú rere lọ́dọ̀ Olúwa.

Ka pipe ipin Òwe 18

Wo Òwe 18:22 ni o tọ