Òwe 19:3 BMY

3 Ìwà òmùgọ̀ ènìyàn fúnra rẹ̀ a pa ẹ̀mí rẹ̀ run;ṣíbẹ̀ ọkàn rẹ̀ yóò máa bínú sí Olúwa.

Ka pipe ipin Òwe 19

Wo Òwe 19:3 ni o tọ