Òwe 23:1 BMY

1 Nígbà tí ìwọ bá jókòó láti bá ìjòyè jẹun,kíyèsí ohun tí ó wà níwájú rẹ gidigidi.

Ka pipe ipin Òwe 23

Wo Òwe 23:1 ni o tọ