Òwe 23:13 BMY

13 Má ṣe fa ọwọ́ ìbáwí sẹ́yìn kúrò lára ọmọdé,nítorí pé bí ìwọ bá fi pàṣán nà án, òun kì yóò kú.

Ka pipe ipin Òwe 23

Wo Òwe 23:13 ni o tọ