Òwe 23:24 BMY

24 Baba olódodo ni yóò yọ̀ gidigidi:ẹni tí ó sì bí ọmọ ọlọ́gbọ́n,yóò ní ayọ̀ nínú rẹ̀.

Ka pipe ipin Òwe 23

Wo Òwe 23:24 ni o tọ