Òwe 29:17 BMY

17 Bá ọmọ rẹ wí, yóò sì fún ọ ní àlàáfíàyóò sì mú inú dídùn wá sí inú ọkàn rẹ.

Ka pipe ipin Òwe 29

Wo Òwe 29:17 ni o tọ