Òwe 29:22 BMY

22 Oníbìínú ènìyàn a ru ìjà sókè,Onínú-fùfù ènìyàn a sì máa dá ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀ṣẹ̀.

Ka pipe ipin Òwe 29

Wo Òwe 29:22 ni o tọ