Òwe 29:7 BMY

7 Olódodo ń ṣaápọn nípa ìdájọ́ òtítọ́ fún àwọn tálákà,ṣùgbọ́n kò sí ohun tí ó kan ènìyàn búburú nínú irú rẹ̀.

Ka pipe ipin Òwe 29

Wo Òwe 29:7 ni o tọ