Òwe 31:15 BMY

15 Ó dìde nígbà tí òkùnkùn sì kùn;ó ṣe oúnjẹ fún ìdílé rẹ̀àti ìpín oúnjẹ fún àwọn ìránṣẹ́-bìnrin rẹ̀.

Ka pipe ipin Òwe 31

Wo Òwe 31:15 ni o tọ