18 Ǹjẹ́, kí oríṣun rẹ di àbùkù fún;kí ó sì yọ nínú aya ìgbà èwe rẹ.
19 Abo àgbọ̀nrín tó dára, ìgalà tí ó wu ni jọjọJẹ́ kí ọmú rẹ̀ tẹ́ ọ lọ́rùn nígbà gbogbojẹ́ kí ìfẹ́ rẹ̀ máa fà ọ́ títí láéláé
20 Ọmọ mi, èéṣe tí ìfẹ́ aṣẹ́wó fi ń fà ọ́tí ìwọ sì ń dì mọ́ ìyàwó ẹlòmíràn?
21 Nítorí ọ̀nà ènìyàn kò farasin rárá fún OlúwaÓ sì ń gbé gbogbo ọ̀nà rẹ̀ yẹ̀wò
22 Ìwà búburú ènìyàn búburú ni yóò mú kó bọ́ sínú okùn;okùn ẹ̀ṣẹ̀ ẹ rẹ̀ dì í le kankan
23 Yóò kú nítorí àìgba ẹ̀kọ́ìwà òmùgọ̀ ara rẹ̀ ló mú kó ṣáko lọ.