1 Ọmọ mi, pa ọ̀rọ̀ mi mọ́,sì fi àwọn òfin mi pamọ́ sínú ọkàn rẹ.
2 Pa òfin mi mọ́, ìwọ yóò sì yètọ́jú ẹ̀kọ́ mi bí ẹyinlójú rẹ
3 Kọ wọ́n sí ọwọ́ òsì rẹ, má ṣe fi jẹunkọ wọ́n sí inú ọkàn rẹ.
4 Wí fún ọgbọ́n pé, “Ìwọ ni arábìnrin mi,”sì pe òye ní ìbátan rẹ;