9 ní ìrọ̀lẹ́ bí oòrùn ṣe ń wọ̀,bí òkùnkùn ṣẹ ń bo ni lára.
10 Bẹ́ẹ̀ ni obìnrin kan jáde wá láti pàdé rẹ̀,ó múra bí aṣẹ́wó pẹ̀lú ètè búburú.
11 (Ó jẹ́ aláriwo àti alágídí,ìdí rẹ̀ kì í jókòó nílé;
12 bí ó ti ń já níhìn ín ní ó ń já lọ́hùn úngbogbo orígun ni ó ti ń ba ní ibùba.)
13 Ó dìí mú, ó sì fẹnu kò ó ní ẹnupẹ̀lú ojú dídín ó wí pé:
14 “Mo ní ọrẹ àlàáfíà ní ilé;lónìí ni mo san ẹ̀jẹ́ mi.
15 Nítorí náà ni mo ṣe jáde wá pádé è rẹ;mo wá ọ káàkiri mo sì ti rí ọ!