1 Ọgbọ́n ti kọ́ ilé rẹ̀,ó ti gbẹ́ òpó o rẹ̀ méjèèjì
2 ó ti fi ilé pọn tí ó ti fọ̀nà rokàó sì ti ṣètò o tábìlì oúnjẹ rẹ̀
3 ó ti rán àwọn ìránṣẹ́bìnrin rẹ̀ jáde, ó sì ń pè,láti ibi tí ó ga jù láàrin ìlú.
4 “Jẹ́ kí gbogbo àwọn aláìgbọ́n wọ ibí wá!”Ó ń wí fún àwọn tí kò lọ́gbọ́n pé
5 “Wá, ẹ wá fẹ́ oúnjẹ misì mu wáìnì tí mo ti pò pọ̀.
6 Fi ìwà àìmọ̀kan rẹ sílẹ̀ ìwọ yóò sì yè;rìn ní ọ̀nà òye.