Jẹnẹsisi 1:8 BM

8 Ọlọrun sọ awọsanma náà ní ojú ọ̀run. Ilẹ̀ ṣú, ilẹ̀ sì tún mọ́, ó di ọjọ́ keji.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 1

Wo Jẹnẹsisi 1:8 ni o tọ