Jẹnẹsisi 1:9 BM

9 Ọlọrun pàṣẹ pé kí omi tí ó wà lábẹ́ ọ̀run wọ́jọ pọ̀ sí ojú kan, kí ìyàngbẹ ilẹ̀ lè farahàn, ó sì rí bẹ́ẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 1

Wo Jẹnẹsisi 1:9 ni o tọ