31 Àwọn ni ọmọ Ṣemu, ní ìdílé ìdílé wọn, olukuluku ní agbègbè tirẹ̀. Oríṣìíríṣìí orílẹ̀-èdè ni wọ́n, wọ́n sì ń sọ oríṣìíríṣìí èdè.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 10
Wo Jẹnẹsisi 10:31 ni o tọ