Jẹnẹsisi 10:32 BM

32 Ìdílé àwọn ọmọ Noa ni wọ́n jẹ́, gẹ́gẹ́ bí ìran wọn ní orílẹ̀-èdè wọn. Lára wọn ni àwọn orílẹ̀-èdè ti tàn ká gbogbo ayé lẹ́yìn ìkún omi.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 10

Wo Jẹnẹsisi 10:32 ni o tọ