Jẹnẹsisi 13:7 BM

7 Ìjà sì ń ṣẹlẹ̀ láàrin àwọn darandaran Abramu ati àwọn ti Lọti. Ní àkókò náà, àwọn ará Kenaani ati àwọn ará Perisi ń gbé ilẹ̀ náà.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 13

Wo Jẹnẹsisi 13:7 ni o tọ