Jẹnẹsisi 13:8 BM

8 Abramu bá sọ fún Lọti pé, “Má jẹ́ kí ìjà bẹ́ sílẹ̀ láàrin èmi pẹlu rẹ, tabi láàrin àwọn darandaran mi ati àwọn tìrẹ. Ṣebí ara kan náà ni wá?

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 13

Wo Jẹnẹsisi 13:8 ni o tọ