Jẹnẹsisi 14:20 BM

20 Ìyìn sì ni fún Ọlọrun Ọ̀gá Ògo,ẹni tí ó bá ọ ṣẹgun àwọn ọ̀tá rẹ.”Abramu bá fún Mẹlikisẹdẹki ní ìdámẹ́wàá gbogbo ìkógun tí ó kó bọ̀.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 14

Wo Jẹnẹsisi 14:20 ni o tọ