21 Ọba Sodomu sọ fún Abramu pé, “Jọ̀wọ́, máa kó gbogbo ìkógun lọ, ṣugbọn dá àwọn eniyan mi pada fún mi.”
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 14
Wo Jẹnẹsisi 14:21 ni o tọ