1 Lẹ́yìn nǹkan wọnyi, OLUWA bá Abramu sọ̀rọ̀ lójú ìran, ó ní, “Má bẹ̀rù Abramu, n óo dáàbò bò ọ́, èrè rẹ yóo sì pọ̀ pupọ.”
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 15
Wo Jẹnẹsisi 15:1 ni o tọ