2 Ṣugbọn Abramu dáhùn pé, “OLUWA Ọlọrun, kí ni o óo fún mi, n kò tíì bímọ títí di ìsinsìnyìí! Ṣé Elieseri ará Damasku yìí ni yóo jẹ́ àrólé mi ni?
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 15
Wo Jẹnẹsisi 15:2 ni o tọ