Jẹnẹsisi 17:20 BM

20 Ní ti Iṣimaeli, mo ti gbọ́ ìbéèrè rẹ, wò ó, n óo bukun òun náà, n óo sì fún un ní ọpọlọpọ ọmọ ati ọmọ ọmọ, yóo jẹ́ baba fún àwọn ọba mejila, n óo sì sọ ọ́ di orílẹ̀ èdè ńlá.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 17

Wo Jẹnẹsisi 17:20 ni o tọ