21 Ṣugbọn n óo fìdí majẹmu mi múlẹ̀ pẹlu Isaaki, tí Sara yóo bí fún ọ ní ìwòyí ọdún tí ń bọ̀.”
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 17
Wo Jẹnẹsisi 17:21 ni o tọ