Jẹnẹsisi 18:7 BM

7 Abrahamu tún yára lọ sinu agbo mààlúù rẹ̀, ó mú ọ̀dọ́ mààlúù kan tí ó lọ́ràá dáradára, ó fà á fún àwọn iranṣẹ rẹ̀, ó ní kí wọ́n yára pa á, kí wọ́n sì sè é.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 18

Wo Jẹnẹsisi 18:7 ni o tọ