Jẹnẹsisi 18:8 BM

8 Ó mú wàràǹkàṣì, ati omi wàrà, ati ẹran ọ̀dọ́ mààlúù tí wọ́n sè, ó gbé wọn kalẹ̀ fún àwọn àlejò náà, ó sì dúró tì wọ́n bí wọ́n ti ń jẹun lábẹ́ igi.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 18

Wo Jẹnẹsisi 18:8 ni o tọ