Jẹnẹsisi 19:37 BM

37 Èyí àkọ́bí bí ọmọkunrin kan, ó sọ ọ́ ní Moabu, òun ni baba ńlá àwọn ẹ̀yà Moabu títí di òní olónìí.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 19

Wo Jẹnẹsisi 19:37 ni o tọ