38 Èyí àbúrò náà bí ọmọkunrin kan, ó sọ ọ́ ní Bẹnami, òun ni baba ńlá àwọn ẹ̀yà Amoni títí di òní olónìí.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 19
Wo Jẹnẹsisi 19:38 ni o tọ