Jẹnẹsisi 20:1 BM

1 Láti ibẹ̀ ni Abrahamu ti lọ sí agbègbè Nẹgẹbu, ó sì ń gbé Gerari, ní ààrin Kadeṣi ati Ṣuri.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 20

Wo Jẹnẹsisi 20:1 ni o tọ