Jẹnẹsisi 20:13 BM

13 Nígbà tí Ọlọrun mú kí n máa káàkiri kúrò ní ilé baba mi, mo wí fún un pé, ‘Oore kan tí o lè ṣe fún mi nìyí: níbi gbogbo tí a bá dé, wí fún wọn pé, arakunrin rẹ ni mí.’ ”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 20

Wo Jẹnẹsisi 20:13 ni o tọ