14 Abimeleki mú aguntan ati mààlúù ati ẹrukunrin ati ẹrubinrin, ó kó wọn fún Abrahamu, ó sì dá Sara, aya rẹ̀, pada fún un.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 20
Wo Jẹnẹsisi 20:14 ni o tọ