3 Ṣugbọn Ọlọrun tọ Abimeleki wá lóru lójú àlá, ó sì wí fún un pé, “O jẹ́ mọ̀! Ikú ti pa ọ́ tán báyìí, nítorí pé obinrin tí o mú sọ́dọ̀, aya aláya ni.”
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 20
Wo Jẹnẹsisi 20:3 ni o tọ