Jẹnẹsisi 21:29 BM

29 Abimeleki bá bi Abrahamu, ó ní, “Kí ni ìtumọ̀ abo ọmọ aguntan meje tí o yà sọ́tọ̀ wọnyi?”

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 21

Wo Jẹnẹsisi 21:29 ni o tọ