30 Abrahamu dá a lóhùn pé, “Gba abo ọmọ aguntan meje wọnyi lọ́wọ́ mi, kí o lè jẹ́ ẹlẹ́rìí mi pé èmi ni mo gbẹ́ kànga yìí.”
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 21
Wo Jẹnẹsisi 21:30 ni o tọ