8 Ọmọ náà dàgbà, ó sì já lẹ́nu ọmú, Abrahamu sì se àsè ńlá ní ọjọ́ tí ọmọ náà já lẹ́nu ọmú.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 21
Wo Jẹnẹsisi 21:8 ni o tọ