Jẹnẹsisi 21:9 BM

9 Ní ọjọ́ kan, Sara rí ọmọ tí Hagari, ará Ijipti bí fún Abrahamu, níbi tí ó ti ń bá Isaaki, ọmọ rẹ̀, ṣeré.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 21

Wo Jẹnẹsisi 21:9 ni o tọ