8 Abrahamu dá a lóhùn pé, “Ọmọ mi, Ọlọrun fúnrarẹ̀ ni yóo pèsè, àgbò tí a óo fi rú ẹbọ sísun náà.” Àwọn mejeeji tún ń bá ìrìn àjò wọn lọ.
Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 22
Wo Jẹnẹsisi 22:8 ni o tọ