Jẹnẹsisi 22:9 BM

9 Nígbà tí wọ́n dé ibi tí Ọlọrun júwe fún Abrahamu, ó tẹ́ pẹpẹ kan níbẹ̀, ó to igi sórí pẹpẹ náà, ó di Isaaki ọmọ rẹ̀ tọwọ́ tẹsẹ̀, ó bá gbé e ka orí igi lórí pẹpẹ tí ó tẹ́.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 22

Wo Jẹnẹsisi 22:9 ni o tọ