Jẹnẹsisi 23:16 BM

16 Abrahamu gbà bí Efuroni ti wí, ó bá wọn irinwo (400) ìwọ̀n ṣekeli fadaka tí Efuroni dárúkọ fún un lójú gbogbo wọn, ó lo ìwọ̀n tí àwọn oníṣòwò ìgbà náà ń lò.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 23

Wo Jẹnẹsisi 23:16 ni o tọ