Jẹnẹsisi 23:17 BM

17 Bẹ́ẹ̀ ni ilẹ̀ Efuroni ní Makipela, tí ó wà ní apá ìhà ìlà oòrùn Mamure ṣe di ti Abrahamu, ati ihò tí ó wà ninu ilẹ̀ náà, ati gbogbo igi tí ó wà ninu rẹ̀ jákèjádò.

Ka pipe ipin Jẹnẹsisi 23

Wo Jẹnẹsisi 23:17 ni o tọ